Gomina Adeleke sọ pe saa awọn alaga atawọn kansilọ APC naa ti pari wi pe bi wọn tun ṣe wa nipo lodi sofin. Ẹwẹ, ẹgbẹ oṣelu APC naa da a pada fun gomina wi pe ko si ohun to jẹ bẹẹ rara.
Arsenal to ti n lewaju lori tabili Champions League lati ibẹrẹ idije naa fiya jẹ ikọ agbabọọlu Kairat Almaty pẹlu ami ayo ...